Text Results

Tune Identifier:"^st_albinus_gauntlett$"
In:texts

Planning worship? Check out our sister site, ZeteoSearch.org, for 20+ additional resources related to your search.
Showing 11 - 11 of 11Results Per Page: 102050
TextAudio

Jesu Ye Titi Aiye

Author: Christian F. Gellert; Anonymous Appears in 1 hymnal Matching Instances: 1 First Line: Jesu ye, titi aiye Lyrics: 1 Jesu ye, titi aiye Eru iku ko ba ni mo; Jesu ye; Nitorina Isa oku ko n’ipa mo. Alleluya! 2 Jesu ye; lat’oni lo Iku je ona si iye; Eyi y’o je ‘tunu wa ‘Gbat’ akoko iku ba de. Alleluya! 3 Jesu ye; fun wa l’o ku Nje Tire ni a o ma se; A o f’okan funfun sin, A o f’ ogo f’Olugbala. Alleluya! 4 Jesu ye; eyi daju Iku at’ipa okunkun Ki y’o le ya ni kuro Ninu ife nla ti Jesu Alleluya! 5 Jesu ye; gbogbo ‘joba L’orun, li aiye, di tire; E je ki a ma tele, Ki a le joba pelu Re. Alleluya! Used With Tune: ST. ALBINUS

Pages


Export as CSV