15889. Kristian Ma Ti 'Wa 'Simi

1 Kristian, ma ti ’wa ’simi,
Gbo b’Angeli re ti nwi;
Ni aarin ota l’o wa;
Maa sora.

2 Ogun orun-apadi,
T’a ko ri, nko ‘ra won jo;
Nwon nso ijafara re;
Maa sora.

3 Wo hamora-orun re,
Wo losan ati loru;
Esu ba, o ndode re;
Maa sora.

4 Awon t’o segun saju,
Nwon nwo wa b’awa ti nja:
Nwon nfi ohun kan wipe,
Maa sora.

5 Gbo b’Oluwa re ti wi,
Eniti iwo feran;
F’oro Re si okan re;
Maa sora.

6 Maa sora bi enipe,
Nibe ni’segun re wa;
Gbadura fun ‘ranlowo;
Maa sora.

Text Information
First Line: Kristian, ma ti ’wa ’simi
Title: Kristian Ma Ti 'Wa 'Simi
English Title: Christian, seek not yet repose
Author: Charlotte Elliott
Translator: Anonymous
Meter: 77.73
Language: Yoruba
Copyright: Public Domain
Tune Information
Name: SAMOS
Composer: William Henry Havergal
Meter: 77.73
Key: A♭ Major
Copyright: Public Domain



Media
Adobe Acrobat image: PDF
MIDI file: MIDI
Noteworthy Composer score: Noteworthy Composer Score
More media are available on the tune authority page.

Suggestions or corrections? Contact us